Gbenga Akinfenwa ~ Aanu Ni Mori Gba

Gbenga Akinfenwa ~ Aanu Ni Mori Gba

Aanu Ni Mori Gba SONG by Gbenga Akinfenwa

Nigerian Renowned Gospel Artist Gbenga Akinfenwa released a single with the live performance music video of the song titled “Aanu Ni Mori Gba”

Stay blessed as you stream and Download this amazing mp3 audio single for free and don’t forget to drop your comment using the comment box below thanks. #NgospelMedia

Check Also:
Boney M. - Rivers Of Babylon Free Christmas Mp3 Song Download

Aanu Ni Mori Gba by Gbenga Akinfenwa Lyrics

Chorus:
Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh.. /2x

Call: ki ma ma ise tori mo dara, tabi tori mo mo aduraa gba
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: ki ma ma ise ile ti mo wa, tabi tori gbogbo iwe ti mo ka
Call: Ki ma ma ise tori moni baba Isale, lo mu kokan mi fi bale.

Check Also:
Lyrics: Unto The King - Frank Edwards

Call: Bi mo ba se njade nile
Aanu!
Call: Bi mo se nkore woke
Aanu!
Call: Mo nsori ire sere
Aanu…ko ma tele mi o

- Adverts -