Yes and Amen ~ Tope Alabi :: Lyrics

Related Posts
1 of 951

Instrumentals

Solo 1
Amin ase ida alamo o
Eni ti o ni a padanu
Iba o toto o Olu imo
Eni ti o ni o ko ni nkankan
Amin aseda

Chorus
Eni ti o ni o ko ni nkankan o
Eni ti o ni o ko ni nkankan
(Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o ko ni nkankan o
Eni ti o ni o ko ni nkankan

Solo 2
Mo wa ri foba to ni di da aiye eeee
Iba re mare e, oni gbede orun
Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo
Bo ti doyi kato
Iba onimo to ga ju ee
Baba ni baba n see
Amin ase ida mo gbe ba fun

Repeat Solo 1

Chorus

Solo 3
O da okun, O da oosa
Alara to fi omi se osho
Iwo to mo ibi eja gba d’odo
Majemu to bu iyo ja okun
Iyanrin te ka aiye
Oda okunkun biri imu
Oda imole oo
Oju orun o ni ilekun oo
Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo
O mu eda gba inu eda waiye
Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo
Ajulo o eni ti o wa o
Ko le mo nkankan
Eni ti o wa e o

Chorus

Solo 4
Majemu alai lepin n lo je
Ijinle alaile tun wo
Irawo nyo lailai lo’nka beni
Osupa nse atokun to ba dale beni o
Ibi gbogbo ni won ti mi ri beni
Oto lo f’ara da orun saiye beni o
O se ojo o tun s’oda e mo beni
Eranko igbo won lo sua beni
Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri tan

Chorus
Eni ti o ri ise e ko ri nkankan o
Eni ti o ri ise e ko ri nkankan o
Eni ti o ri ise e ko ri nkankan o
Koda ko ri ra e pa beni
Eni ti o ri ise e, ko ri nkankan o
Ooo
Eni ti o ri ise e ko ri nkankan o

Instrumental…

Solo 5
O se mi dabi ohun, opin mi ni ipin
Ti ko jo teni keji
Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun
Adagbaeyin ni mi o wa fi mi joba
Ohun gbogbo ti o ti ko da
O da mi, o su mi ni ire
Emi ni beeni, ase olodumare ni
Amin lohun, emi lami
Ayanmo ogo, ogun mi ni
Eda emi lo fi se iranse mi
Akori iran mi, oju ogo re ni
Mo ni imi iye e ninu
Eni o ri mi, ko ri nkankan
Eee eni ti o ri mi
Ko ri nkankan

Chorus:
Eni ti o ri mi
Ko ri ise Olorun wo
Eni ti o ri mi ke, ko ri nkan
Eni ti o ri mi
Ko ri nkankan o
E o foju
Eni ti o ri mi, ko rise Olorun 0o
Ko ri Olodumare, oda mi bi ohun ni
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan
Eni ti o ri mi, ko ri ise Olorun wo
Ooooooo
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan o
Eni ti o ri mi, ko ri ise Olorun wo
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan

Bridge:
Ami lawa je si iwo ami
Beni ire loje ki aiye wa o
Olorun l’amin
Amin lo n f’amin wa han
Aiye at’orun lami yen
Aseda ni amin
Oro re lo je ki a ma wa
Olorun l’amin

Adlibs
Response: Amin, Amin, Amin, Amin o

- Adverts -